Yoruba Bible
Romu 11:24
Nitori bi a ti ke iwọ kuro lara igi oróro igbẹ́ nipa ẹda, ti a si lọ́ iwọ sinu igi oróro rere lodi si ti ẹda: melomelo li a o lọ́ awọn wọnyi, ti iṣe ẹka-iyẹka sara igi oróro wọn? Àánú Ọlọrun Wà fún Gbogbo Eniyan
Open Bible reader