Skip to content

Yoruba Bible

Luku 9:48

O si wi fun wọn pe, Ẹnikẹni ti o ba gbà ọmọde yi nitori orukọ mi, o gbà mi: ati ẹnikẹni ti o ba gbà mi, o gbà ẹniti o rán mi: nitori ẹniti o ba kere ju ninu gbogbo nyin, on na ni yio pọ̀. Ẹni Tí Kò Bá Lòdì sí Yín, Tiyín ni (Mak 9:38-40)

Open Bible reader