Skip to content

Yoruba Bible

Luku 10:24

Nitori mo wi fun nyin, Woli ati ọba pipọ li o nfẹ lati ri ohun ti ẹnyin nri, nwọn kò si ri wọn, ati lati gbọ ohun ti ẹnyin ngbọ́, nwọn ko si gbọ́ wọn, Aláàánú Ará Samaria

Open Bible reader