Yoruba Bible
Efesu 4:16
Lati ọdọ ẹniti ara na ti a nso ṣọkan pọ, ti o si nfi ara mọra, nipa gbogbo orike ipese, (gẹgẹ bi iṣẹ olukuluku ẹya-ara ni ìwọn tirẹ̀) o nmu ara na bi si i fun idagbasoke on tikararẹ ninu ifẹ. Ìgbé-Ayé ti Àtijọ́ ati ti Ìsinsìnyìí
Open Bible reader