Skip to content

Yoruba Bible

Kolose 2:19

Ti kò si di Ori nì mu ṣinṣin, lati ọdọ ẹniti a nti ipa orike ati iṣan pese fun gbogbo ara, ti a si nso o ṣọkan pọ, ti o si ndagba nipa ibisi Ọlọrun. Ìgbé-Ayé Titun ninu Kristi

Open Bible reader