Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 28:15

Ati lati ibẹ nigbati awọn arakunrin gburó wa, nwọn wá titi nwọn fi de Apii Foroni, ati Arojẹ mẹta, lati pade wa: nigbati Paulu si ri wọn, o dupẹ lọwọ Ọlọrun, o mu ọkàn le. Paulu Waasu ní Romu

Open Bible reader