Yoruba Bible
Ise Awọn Aposteli 26:11
Nigbapipọ ni mo ṣẹ́ wọn niṣẹ ninu gbogbo sinagogu, mo ndù u lati mu wọn sọ ọrọ-odi; nigbati mo ṣoro si wọn gidigidi, mo ṣe inunibini si wọn de àjeji ilu. Paulu Sọ Bí Ó Ti Ṣe Di Onigbagbọ (A. Apo 9:1-19; 22:6-16)
Open Bible reader