Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 22:5

Bi olori alufa pẹlu ti jẹ mi li ẹri, ati gbogbo ajọ awọn alàgba: lọwọ awọn ẹniti mo si gbà iwe lọ sọdọ awọn arakunrin, ti mo si lọ si Damasku lati mu awọn ti o wà nibẹ̀ ni didè wá si Jerusalemu, lati jẹ wọn niyà. Paulu Sọ Bí Ó Ṣe Di Onigbagbọ (A. Apo 9:1-19; 26:12-18)

Open Bible reader