Yoruba Bible
Ise Awọn Aposteli 22:29
Nitorina awọn ti o mura lati bi i lẽre kuro lọdọ rẹ̀: lojukanna olori-ogun pẹlu si bẹ̀ru, nigbati o mọ̀ pe ara Romu ni iṣe, ati nitori o ti dè e. Paulu Lọ Siwaju Àwọn Ìgbìmọ̀ Juu
Open Bible readerYoruba Bible
Nitorina awọn ti o mura lati bi i lẽre kuro lọdọ rẹ̀: lojukanna olori-ogun pẹlu si bẹ̀ru, nigbati o mọ̀ pe ara Romu ni iṣe, ati nitori o ti dè e. Paulu Lọ Siwaju Àwọn Ìgbìmọ̀ Juu
Open Bible reader