Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 12:19

Nigbati Herodu si wá a kiri, ti kò si ri i, o wádi awọn ẹ̀ṣọ, o paṣẹ pe, ki a pa wọn. O si sọkalẹ lati Judea lọ si Kesarea, o si joko nibẹ̀. Bí Hẹrọdu Ṣe Kú

Open Bible reader