Skip to content

Yoruba Bible

Sekariah 7:7

Wọnyi kì ọ̀rọ ti Oluwa ti kigbe lati ọdọ awọn woli iṣãju wá, nigbati a ngbe Jerusalemu, ti o si wà li alafia, pẹlu awọn ilu rẹ̀ ti o yi i ka kiri, nigbati a ngbe gusù ati pẹtẹlẹ? Àìgbọràn ló fa Ìkólọ-sóko-Ẹrú

Open Bible reader