Skip to content

Yoruba Bible

Orin Dafidi 109:3

Nwọn si fi ọ̀rọ irira yi mi ka kiri; nwọn si mba mi ja li ainidi.

Open Bible reader