Skip to content

Yoruba Bible

Orin Dafidi 109:29

Jẹ ki a fi ìtiju wọ̀ awọn ọta mi li aṣọ, ki nwọn ki o si fi idaru-dapọ̀ wọn bò ara, bi ẹnipe ẹ̀wu.

Open Bible reader