Yoruba Bible
Nehemiah 7:3
Mo si wi fun wọn pe, Ẹ má jẹ ki ilẹkùn odi Jerusalemu ṣi titi õrùn o fi mú; bi nwọn si ti duro, jẹ ki wọn se ilẹkùn, ki nwọn si há wọn, ki nwọn si yan ẹ̀ṣọ ninu awọn ti ngbe Jerusalemu, olukuluku ninu iṣọ rẹ̀, ati olukuluku ninu ile rẹ̀. Orúkọ Àwọn tí Wọ́n Pada láti Oko Ẹrú (Ẹsr 2:1-70)
Open Bible reader