Yoruba Bible
Marku 3:6
Awọn Farisi jade lọ lojukanna lati ba awọn ọmọ-ẹhin Herodu gbìmọ pọ̀ si i, bi awọn iba ti ṣe pa a. Ọpọlọpọ Eniyan Lẹ́bàá Òkun
Open Bible readerYoruba Bible
Awọn Farisi jade lọ lojukanna lati ba awọn ọmọ-ẹhin Herodu gbìmọ pọ̀ si i, bi awọn iba ti ṣe pa a. Ọpọlọpọ Eniyan Lẹ́bàá Òkun
Open Bible reader