Yoruba Bible
Marku 2:17
Nigbati Jesu gbọ́, o wi fun wọn pe, Awọn ti ara wọn le kì iwá oniṣegun, bikoṣe awọn ti ara wọn ko da: Emi ko wá lati pè awọn olododo, bikoṣe awọn ẹlẹṣẹ si ironupiwada. Ìbéèrè Nípa Ààwẹ̀ Gbígbà (Mat 9:14-17; Luk 5:33-39)
Open Bible reader