Skip to content

Yoruba Bible

Marku 16:18

Nwọn o si ma gbé ejò lọwọ; bi nwọn ba si mu ohunkohun ti o li oró, kì yio pa wọn lara rara: nwọn o gbé ọwọ́ le awọn ọlọkunrun, ara wọn ó da. Ìgòkè-Re-Ọ̀run Ti Jesu (Luk 24:50-53; A. Apo 1:9-11)

Open Bible reader