Skip to content

Yoruba Bible

Marku 15:32

Jẹ ki Kristi, Ọba Israeli, sọkalẹ lati ori agbelebu wá nisisiyi, ki awa ki o le ri i, ki a si le gbagbọ́. Awọn ti a kàn mọ agbelebu pẹlu rẹ̀ si nkẹgan rẹ̀. Ikú Jesu (Mat 27:45-56; Luk 23:44-49; Joh 19:28-30)

Open Bible reader