Yoruba Bible
Marku 14:21
Nitõtọ Ọmọ-enia nlọ bi a ti kọwe nipa tirẹ̀: ṣugbọn egbé ni fun ọkunrin na, lọdọ ẹniti a gbé ti fi Ọmọ-enia hàn! iba san fun ọkunrin na, bi o ṣepe a kò bí i. Oúnjẹ Alẹ́ Oluwa (Mat 26:26-30; Luk 22:15-20; 1 Kọr 11:23-25)
Open Bible reader