Yoruba Bible
Marku 12:34
Nigbati Jesu ri i pe o fi òye dahùn, o wi fun u pe, Iwọ kò jìna si ijọba Ọlọrun. Lẹhin eyini, kò si ẹnikan ti o jẹ bi i lẽre ohunkan mọ́. Ìbéèrè Jesu Nípa Ọmọ Dafidi (Mat 22:41-46; Luk 20:41-44)
Open Bible readerYoruba Bible
Nigbati Jesu ri i pe o fi òye dahùn, o wi fun u pe, Iwọ kò jìna si ijọba Ọlọrun. Lẹhin eyini, kò si ẹnikan ti o jẹ bi i lẽre ohunkan mọ́. Ìbéèrè Jesu Nípa Ọmọ Dafidi (Mat 22:41-46; Luk 20:41-44)
Open Bible reader