DaBible
Luke 9:45
Yoruba
Ṣugbọn ọ̀rọ na ko yé wọn, o si ṣú wọn li oju, bẹ̃ni nwọn kò si mọ̀ ọ: ẹ̀ru si mba wọn lati bère idi ọ̀rọ na. Ta Ni Ẹni Tí Ó Ṣe Pataki Jùlọ? (Mat 18:1-5; Mak 9:33-37)
English / KJV
But they understood not this saying, and it was hid from them, that they perceived it not: and they feared to ask him of that saying.