Skip to content

Yoruba Bible

Luku 8:25

O si wi fun wọn pe, Igbagbọ́ nyin dà? Bi ẹ̀ru ti mba gbogbo wọn, ti hà si nṣe wọn, nwọn mbi ara wọn pe, irú ọkunrin kili eyi! nitori o ba ẹfufu on riru omi wi, nwọn si gbọ́ tirẹ̀. Jesu Wo Wèrè Ará Geraseni Sàn (Mat 8:28-34; Mak 5:1-20)

Open Bible reader