Skip to content

Yoruba Bible

Luku 21:24

Nwọn o si ti oju idà ṣubu, a o si dì wọn ni igbekun lọ si orilẹ-ède gbogbo: Jerusalemu yio si di itẹmọlẹ li ẹsẹ awọn Keferi, titi akoko awọn Keferi yio fi kún. Àkókò Tí Ọmọ-Eniyan Yóo Dé (Mat 24:29-31; Mak 13:24-27)

Open Bible reader