Skip to content

Yoruba Bible

Johannu 7:31

Ọ̀pọ ninu ijọ enia si gbà a gbọ́, nwọn si wipe, Nigbati Kristi na ba de, yio ha ṣe iṣẹ àmi jù wọnyi lọ, ti ọkunrin yi ti ṣe? Wọ́n Rán Àwọn Oníṣẹ́ Lọ Mú Jesu

Open Bible reader