Skip to content

Yoruba Bible

Johannu 2:12

Lẹhin eyi, o sọkalẹ lọ si Kapernamu, on ati iya rẹ̀ ati awọn arakunrin rẹ̀, ati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀: nwọn kò si gbé ibẹ̀ li ọjọ pupọ. Jesu Lòdì sí Lílò tí Wọn Ń Lo Tẹmpili Bí Ọjà (Mat 21:12-13; Mak 11:15-17; Luk 19:45-46)

Open Bible reader