Yoruba Bible
Johannu 19:27
Lẹhin na li o si wi fun ọmọ-ẹhin na pe, Wò iya rẹ! Lati wakati na lọ li ọmọ-ẹhin na si ti mu u lọ si ile ara rẹ̀. Ikú Jesu (Mat 27:45-56; Mak 15:33-41; Luk 23:44-49)
Open Bible readerYoruba Bible
Lẹhin na li o si wi fun ọmọ-ẹhin na pe, Wò iya rẹ! Lati wakati na lọ li ọmọ-ẹhin na si ti mu u lọ si ile ara rẹ̀. Ikú Jesu (Mat 27:45-56; Mak 15:33-41; Luk 23:44-49)
Open Bible reader