Yoruba Bible
Johannu 18:18
Awọn ọmọ-ọdọ ati awọn onṣẹ si duro nibẹ̀, awọn ẹniti o ti daná ẹyín; nitori otutù mu, nwọn si nyána: Peteru si duro pẹlu wọn, o nyána. Anna Bi Jesu nípa Ẹ̀kọ́ Rẹ̀ (Mat 26:59-66; Mak 14:55-64; Luk 22:66-71)
Open Bible reader