Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 46:26

Emi o si fi wọn le ọwọ awọn ti nwá ẹmi wọn, ati le ọwọ Nebukadnessari, ọba Babeli, ati le ọwọ awọn iranṣẹ rẹ̀: lẹhin na, a o si mã gbe inu rẹ̀, gẹgẹ bi ìgba atijọ, li Oluwa wi. OLUWA Yóo Gba Àwọn Eniyan Rẹ̀ Là

Open Bible reader