Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 39:14

Ani nwọn ranṣẹ nwọn si mu Jeremiah jade ni àgbala ile-tubu, nwọn si fi fun Gedaliah, ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani, pe ki o mu u lọ si ile: bẹ̃ni o ngbe ãrin awọn enia. Ìrètí Wà fún Ebedmeleki

Open Bible reader