Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 39:10

Ṣugbọn Nebusaradani, balogun iṣọ, si mu diẹ ninu awọn enia, ani awọn talaka ti kò ni nkan rara, joko ni ilẹ Juda, o si fi ọgba-àjara ati oko fun wọn li àkoko na. Wọ́n Dá Jeremiah Sílẹ̀

Open Bible reader