Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 16:15

Ṣugbọn, Oluwa mbẹ ti o mu awọn ọmọ Israeli jade wá kuro ni ilẹ ariwa, ati kuro ni ilẹ nibiti o ti lé wọn si: emi o si tun mu wọn wá si ilẹ wọn, eyiti mo fi fun awọn baba wọn. Ìjìyà Tí ń Bọ̀

Open Bible reader