Skip to content

Yoruba Bible

Jeremiah 12:6

Nitori pẹlupẹlu, awọn arakunrin rẹ, ati ile baba rẹ, awọn na ti hùwa ẹ̀tan si ọ, lõtọ, awọn na ti ho le ọ: Má gbẹkẹle wọn, bi nwọn tilẹ ba ọ sọ̀rọ daradara. OLUWA Káàánú Àwọn Eniyan Rẹ̀

Open Bible reader