Yoruba Bible
Jeremiah 12:13
Nwọn ti gbin alikama, ṣugbọn nwọn o ka ẹ́gun, nwọn ti fi irora ẹ̀dun mu ara wọn, ṣugbọn nwọn kì yio ri anfani: ki oju ki o tì nyin nitori ère nyin, nitori ibinu gbigbona Oluwa. Ìlérí OLUWA fún Àwọn Aládùúgbò Israẹli
Open Bible reader