Skip to content

Yoruba Bible

Jakobu 3:12

Ẹnyin ará mi, igi ọpọtọ ha le so eso olifi bi? tabi ajara le so eso ọpọtọ? bẹ̃li orisun kan kò le sun omiró ati omi tutù. Ọgbọ́n láti Òkè Wá

Open Bible reader