Skip to content

Yoruba Bible

Isaiah 26:19

Awọn okú rẹ yio yè, okú mi, nwọn o dide. Ẹ ji, ẹ si kọrin, ẹnyin ti ngbe inu ekuru: nitori ìri rẹ ìri ewebẹ̀ ni, ilẹ yio si sọ awọn okú jade. Ìdájọ́ ati Ìmúpadàbọ̀sípò

Open Bible reader