Yoruba Bible
Genesisi 11:9
Nitorina li a ṣe npè orukọ ilu na ni Babeli; nitori ibẹ̀ li OLUWA gbe dà ède araiye rú, lati ibẹ̀ lọ OLUWA si tú wọn ká kiri si ori ilẹ gbogbo. Àwọn Ìran Ṣemu (1 Kron 1:24-27)
Open Bible readerYoruba Bible
Nitorina li a ṣe npè orukọ ilu na ni Babeli; nitori ibẹ̀ li OLUWA gbe dà ède araiye rú, lati ibẹ̀ lọ OLUWA si tú wọn ká kiri si ori ilẹ gbogbo. Àwọn Ìran Ṣemu (1 Kron 1:24-27)
Open Bible reader