DaBible
Ephesians 2:10
Yoruba
Nitori awa ni iṣẹ ọwọ́ rẹ̀ ti a ti dá ninu Kristi Jesu fun iṣẹ rere, ti Ọlọrun ti pèse tẹlẹ, ki awa ki o le mã rìn ninu wọn. Ọ̀kan ninu Kristi
English / KJV
For we are his workmanship, created in Christ Jesus unto good works, which God hath before ordained that we should walk in them.