Skip to content

Yoruba Bible

Danieli 11:20

Nigbana ni ẹnikan yio dide ni ipò rẹ̀ ti yio mu agbowode kan rekọja ninu ogo ijọba (ilẹ Juda): ṣugbọn niwọn ijọ melokan li a o si pa a run, kì yio ṣe nipa ibinu tabi loju ogun. Ọba Burúkú tí Ó Jẹ ní Siria

Open Bible reader