Skip to content

Yoruba Bible

Kolose 2:5

Nitoripe bi emi kò tilẹ si lọdọ nyin li ara, ṣugbọn emi mbẹ lọdọ nyin li ẹmí, mo nyọ̀, mo si nkiyesi eto nyin, ati iduroṣinṣin igbagbọ́ nyin ninu Kristi. Ìgbé-Ayé Lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́ ninu Kristi

Open Bible reader