Yoruba Bible
Ise Awọn Aposteli 26:18
Lati là wọn li oju, ki nwọn ki o le yipada kuro ninu òkunkun si imọlẹ, ati kuro lọwọ agbara Satani si Ọlọrun, ki nwọn ki o le gbà idariji ẹ̀ṣẹ, ati ogún pẹlu awọn ti a sọ di mimọ́ nipa igbagbọ ninu mi. Ẹ̀rí tí Paulu Jẹ́ fún Àwọn Juu ati fún Àwọn Orílẹ̀-Èdè Yòókù
Open Bible reader