Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 24:23

O si paṣẹ fun balogun ọrún kan pe, ki o mã ṣe itọju Paulu, ki o si bùn u làye, ati pe ki o máṣe dá awọn ojulumọ̀ rẹ̀ lẹkun, lati ma ṣe iranṣẹ fun u. Wọ́n Ti Paulu Mọ́lé

Open Bible reader