Yoruba Bible
Ise Awọn Aposteli 23:11
Li oru ijọ na Oluwa duro tì i, o si wipe, Tujuka: nitori bi iwọ ti jẹri fun mi ni Jerusalemu, bẹ̃ni iwọ kò le ṣaijẹrí ni Romu pẹlu. Àwọn Juu Dìtẹ̀ láti Pa Paulu
Open Bible readerYoruba Bible
Li oru ijọ na Oluwa duro tì i, o si wipe, Tujuka: nitori bi iwọ ti jẹri fun mi ni Jerusalemu, bẹ̃ni iwọ kò le ṣaijẹrí ni Romu pẹlu. Àwọn Juu Dìtẹ̀ láti Pa Paulu
Open Bible reader