Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 21:26

Nigbana ni Paulu mu awọn ọkunrin na; ni ijọ keji o ṣe iwẹnumọ pẹlu wọn, o si wọ̀ inu tẹmpili lọ, o sọ ìgba ti ọjọ ìwẹ̀numọ́ na yio pé titi a fi rubọ fun olukuluku wọn. Wọ́n Mú Paulu ninu Tẹmpili

Open Bible reader