Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 21:16

Ninu awọn ọmọ-ẹhin lati Kesarea ba wa lọ, nwọn si mu Mnasoni ọmọ-ẹhin lailai kan pẹlu wọn, ará Kipru, lọdọ ẹniti awa ó gbé wọ̀. Paulu Lọ Bẹ Jakọbu Wò

Open Bible reader