Skip to content

Yoruba Bible

Ise Awọn Aposteli 20:16

Paulu sá ti pinnu rẹ̀ lati mu ọkọ̀ lọ niha Efesu, nitori ki o ma ba fi igba na joko ni Asia: nitori o nyára bi yio ṣe iṣe fun u, lati wà ni Jerusalemu li ọjọ Pentikosti. Paulu Bá Àwọn Alàgbà Efesu Sọ̀rọ̀

Open Bible reader