Psalms 87 - Listen Online
Read Psalms 87
1 IPILẸ rẹ̀ mbẹ lori òke mimọ́ wọnni.
1 His foundation is in the holy mountains.
2 Oluwa fẹ ẹnu-ọ̀na Sioni jù gbogbo ibujoko Jakobu lọ.
2 The LORD loveth the gates of Zion more than all the dwellings of Jacob.
3 Ohun ogo li a nsọ niti rẹ? Ilu Ọlọrun!
3 Glorious things are spoken of thee, O city of God. Selah.
4 Emi o da orukọ Rahabu ati Babeli lãrin awọn ti o mọ̀ mi: kiyesi Filistia ati Tire, pẹlu Etiopia: a bi eleyi nibẹ.
4 I will make mention of Rahab and Babylon to them that know me: behold Philistia, and Tyre, with Ethiopia; this man was born there.
5 Ati ni Sioni li a o wipe: ọkunrin yi ati ọkunrin nì li a bi ninu rẹ̀: ati Ọga-ogo tikararẹ̀ ni yio fi ẹsẹ rẹ̀ mulẹ.
5 And of Zion it shall be said, This and that man was born in her: and the highest himself shall establish her.
6 Oluwa yio kà, nigbati o ba nkọ orukọ awọn enia, pe, a bi eleyi nibẹ.
6 The LORD shall count, when he writeth up the people, that this man was born there. Selah.
7 Ati awọn olorin ati awọn ti nlu ohun-elo orin yio wipe: Gbogbo orisun mi mbẹ ninu rẹ.
7 As well the singers as the players on instruments shall be there: all my springs are in thee.