Skip to content

Psalms 3 - Listen Online

Loading Bible...
Read Psalms 3

1 OLUWA, awọn ti nyọ mi li ẹnu ti npọ̀ to yi! ọ̀pọlọpọ li awọn ti o dide si mi.

1 LORD, how are they increased that trouble me! many are they that rise up against me.

2 Ọ̀pọlọpọ li awọn ti o nwi niti ọkàn mi pe, Iranlọwọ kò si fun u nipa ti Ọlọrun.

2 Many there be which say of my soul, There is no help for him in God. Selah.

3 Ṣugbọn iwọ, Oluwa, li asà fun mi; ogo mi; ati olugbe ori mi soke.

3 But thou, O LORD, art a shield for me; my glory, and the lifter up of mine head.

4 Emi fi ohùn mi kigbe si Oluwa, o si gbohùn mi lati òke mimọ́ rẹ̀ wá.

4 I cried unto the LORD with my voice, and he heard me out of his holy hill. Selah.

5 Emi dubulẹ, mo si sùn; mo si ji; nitori ti Oluwa tì mi lẹhin,

5 I laid me down and slept; I awaked; for the LORD sustained me.

6 Emi kì yio bẹ̀ru ọ̀pọlọpọ enia, ti nwọn rọ̀gba yi mi ka.

6 I will not be afraid of ten thousands of people, that have set themselves against me round about.

7 Dide Oluwa; gbà mi, Ọlọrun mi: nitori iwọ li o lù gbogbo awọn ọta mi li egungun ẹrẹkẹ; iwọ si ká ehin awọn enia buburu.

7 Arise, O LORD; save me, O my God: for thou hast smitten all mine enemies upon the cheek bone; thou hast broken the teeth of the ungodly.

8 Ti Oluwa ni igbala: ibukún rẹ si mbẹ lara awọn enia rẹ.

8 Salvation belongeth unto the LORD: thy blessing is upon thy people. Selah.