Skip to content

Yoruba Bible

Sekariah 5:4

Emi o mu u jade, ni Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, yio si wọ̀ inu ile olè lọ, ati inu ile ẹniti o ba fi orukọ mi bura eke: yio si wà li ãrin ile rẹ̀, yio si run u pẹlu igi ati okuta inu rẹ̀. Ìran nípa Obinrin Tó Wà ninu Apẹ̀rẹ̀

Open Bible reader