Skip to content

Yoruba Bible

Numeri 4:20

Ṣugbọn nwọn kò gbọdọ wọle lọ lati wò ohun mimọ́ ni iṣẹju kan, ki nwọn ki o má ba kú. Iṣẹ́ Àwọn Ọmọ Lefi – Ìdílé Geriṣoni

Open Bible reader