Skip to content

Yoruba Bible

Numeri 19:10

Ki ẹniti o si kó ẽru ẹgbọrọ abomalu na ki o fọ̀ aṣọ rẹ̀, ki o si jẹ́ alaimọ́ titi di aṣalẹ: yio si jẹ́ ilana titilai, fun awọn ọmọ Israeli, ati fun alejò ti nṣe atipo ninu wọn. Òfin Tí ó Jẹ Mọ́ Fífi Ara Kan òkú

Open Bible reader